_id
stringlengths
17
21
url
stringlengths
32
377
title
stringlengths
2
120
text
stringlengths
100
2.76k
20231101.yo_822_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Abeokuta je ilu ni ti o gbajumo nile Yoruba, lapa iwo-oorun orile-ede Naijiria.. O je olu-ilu ipinle Ogun ti o tedo si agbegbe ti o kun fun Apata nla nla. Idi niyi ti won fi n pee ni Abeokuta. Ibe ni Oke Olumo (Olumo Rock) fikale si.
20231101.yo_822_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ó se pàtàkì láti mọ díẹ̀ nípa ìtàn ilẹ̀ Ẹ̀gbá àti irú ènìyàn tí ń gbé ìlú Ẹ̀gbá. Ìdí èyí ni pé yóò jẹ́ ohun ìrànlọ́wọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan tó yẹ ní mímọ̀ nínú orin ògódò. Fún ìdí pàtàkì yìí, n ó ò pín àkòrí yìí si ọ̀nà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.
20231101.yo_822_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ onímọ̀ ló ti sọ nípa bí a ti se tẹ ilẹ̀ Ẹ̀gbá dó, tí wọn sí tì gbé àbọ̀ ìwádìí wọn fún aráyé rí. Ara irú àwọn báyìí ni Samuel Johnson, Sàbírì Bíòbákú, Ajísafẹ́, Délànà àti àwọn mìíràn tó jẹ́ òpìtàn àtẹnudẹ́nu.
20231101.yo_822_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Johnson gbà pé Ọ̀yọ́ ni àwọn Ẹ̀gbá ti wá. O ní àwọn ẹ̀yà Ẹ̀gbá tòótọ́ lé ti orírun wọn de Ọ̀yọ́. ó tún tẹ̀ síwájú síi pé ọmọ àlè tàbí ẹrú ni Ẹ̀gbá tí kò bá ní orírun láti Ọ̀yọ́. Àwọn olóyè wọn wà lára àwọn Ẹ̀sọ́ Aláàfin láyé àtijọ́, àtipé àwọn olóyè yìí ló sá wá sí Abẹ́òkúta lábẹ́ olórí wọn tó jẹ́ àbúrò ọba Ọ̀yọ́ nígbà náà.
20231101.yo_822_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Délànà ní tirẹ̀ ní etí ilé-ifẹ̀ ni àwọn Ẹ̀gbá tó kọ́kọ́ dé tẹ̀ dó sí. Àwọn ni ó pè ní Ẹ̀gbá Gbàgùrà. Wọ́n dúró súú sùù súú káàkiri. Olú ìlú wọn sì ni “ÌDDÓ” tí ó wà níbi tí Ọ̀yọ́ wà báyìí. Àwọn ìsí kejì sun mọ ìsàlẹ̀ díẹ̀. Wọ́n kọjá odò ọnà. Àwọn ni Ẹ̀gbá òkè-ọnà. Òsilẹ̀ ni ọba wọn. Òkó ni olú ìlú wọn .Ẹ̀gbá Aké ló dé gbẹ̀yìn.
20231101.yo_822_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ajísafẹ́ ní ọ̀tẹ̀ ló lé àwọn Ẹ̀gbá kúrò ni ilé- ifẹ̀ wá Kétu. Láti Kétu ni wọn ti wá sí Igbó- Ẹ̀gbá kí wọn to de Abẹ́òkúta ní 1830. Sàbúrí Bíòbákú náà faramọ́ èyí.
20231101.yo_822_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Lọ́rọ̀ kan sá, àwọn Ẹ̀gbá ti ilé- ifẹ̀ wá, wọ́n ni ohun i se pẹ̀lú oko Àdágbá, Kétu, àti igbó-Ẹ̀gbá.
20231101.yo_822_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ìtàn tún fi yé ni síwájú sii pé ìlú Ẹ̀gbá pọ̀ ní orílẹ̀ olúkúlùkù ló sì ń ní ọba tirẹ̀, fífọ́ tí orílẹ́ Ẹ̀gbá fọ́ lò gbé wọn dé ibi tí wọ́n wà báyìí. Gẹ́gẹ́ bí Ìtàn ti sọ, 1821 ni Ìjà tó fọ́ gbogbo Ìlú Ẹ̀gbá ti sẹlẹ̀. Ohun kékeré ló dá Ìjà sílẹ̀ láàárín àwọn òwu àti àwọn Ìjẹ̀bú ni ọjà Apòmù, Ogun Ọ̀yọ́ àti tí ifẹ̀ dà pọ̀ mọ́ ogun Ìjẹ̀bú láti bá Òwu jà. Àgbáríjọ ogun yìí dé ìlú àwọn Òwu ní tọ̀ọ̀ọ́tọ́ sùgbọ́n àwọn Òwu lé wọn padà títí wọ́n fi dé àárín àwọn Gbágùrá to wa ni Ìbàdàn. Inú àwọn Gbágùrá kò dùn sí è́yí wọ́n ti lérò pé ogun yóò kó àwọn Òwu. Èyí náà ló sì mú àwọn Gbágùrá tún gbárajọ láti pẹ̀lú ogun Ọ̀yọ́, Ìjẹ̀bú àti ifẹ̀ kí wọn le borí ogun Òwu. Wọ́n sẹ́gun lóòótọ́ sùgbọ́n lánlẹ́yìn, àkàrà Ríyìíkẹ́ ni ọ̀rọ̀ náà dà nígbẹ̀yìn. Òjò ń podídẹrẹ́ ni, àwòko ń yọ̀. Kò pẹ́ ẹ̀ ni ogun Ìjẹ̀bú, Ìjẹ̀sà, Ọ̀yọ́ àti ifẹ̀ rí i mọ́ pé àsé àwọn Ẹ̀gbá kò nífẹ̀ẹ́ ara wọn, wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ tẹ̀ǹbẹ̀ lẹ̀kun sí àwọn Ẹ̀gbá. Wọn fẹ́rẹ̀ẹ́ kó gbogbo Ìlú wọn tán lọ́kọ̀ọ̀kan.
20231101.yo_822_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Èyí tí ó wá burú jù níbẹ̀ ni ti IKÚ Ẹ́GẸ́ tó jẹ olóyè ifẹ̀ kan. Lámọ́di asíwájú Ẹ̀gbá kan ló páa nígbà tí ǹ dìtẹ̀ mọ ọn. Sùgbọ́n àwọn ọ̀tá kò sàì pa òun náà sán.
20231101.yo_822_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Àwọn babaláwo wọn gbé ọ̀pẹ̀lẹ̀ sánlẹ̀, wọn rí odù òfúnsàá. Wọ́n kifá lọ wọ́n kifá bọ̀, wọ́n ní wọn yóò dé Abẹ́òkúta, àwọn aláwọ̀ funfun yóò sì wá láti bá wọn dọ́rẹ̀ẹ́. Àwọn babaláwo wọn náà ni Tẹ́jú osó láti Ìkìjà Òjo (a ń-là-lejì- ogbè) ara Ìlúgùn àti Awóbíyìí ará irò.
20231101.yo_822_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
1830 Sódẹkẹ́ lo sáájú pẹ̀lú àwọn Ẹ̀gbá Aké. Balógun Ìlúgùn kó Ẹ̀gbá òkè-ọnà kẹ́yìn. Wọn kò rántí osù tí wọ́n dé Abẹ́òkúta mọ́ sùgbọ́n àsìkò òjò ni.
20231101.yo_822_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Nígbà tí wọn kọ́kọ́ dé, wọ́n do sí itòsí Olúmọ, olúkúlùkù ìlú sa ara wọn jọ, wọn do kiri Ẹ̀gbá Aké, Ẹ̀gbá òkè-ọnà àti Ẹ̀gbá Gbágùrá ló kọ́kọ́ dé sí Abẹ́òkúta. Ni 1831 ni àwọn Òwu sẹ̀sẹ̀ wá bá wọn tí àwọn Ẹ̀gbá sì gbà wọ́n tọwọ́ tẹsẹ̀. Àwọn Ẹ̀gbádò tí wọ́n bá ní Ìbarà ló sọ wọ́n ni Ẹ̀gbá, nínú ọ̀rọ̀ “Ẹ̀GBÁLUGBÓ” ni wọ́n sì tí fa ọ̀rọ̀ náà yọ. Àwọn òpìtàn ní àwọn Ẹ̀gbádò ni ń gbé ìpadò nígbà tí àwọn Ẹ̀gbá ní gbé ni òkè ilẹ̀. Òpìtàn míìràn tún ní ìtumọ̀ Ẹ̀gbá ni “Ẹ GBÀ Á “ lálejò nítorí pé wọ́n gba àwọn Òwu àti àwọn mìíràn tí wọ́n ń wá abẹ́ ààbò sá sí mọ́ra.
20231101.yo_822_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ẹ̀yà orísìírísìí tó wà nílẹ̀ Ẹ̀gbá ló jẹ́ kí ó di ìlú ń lá, pẹ̀lú ìjọba àkóso tó lágbára ogun ló sọ ọ́ di kékéré bó ti wàyìÍ. Ní apá Àríwá, ó fẹ̀ dé odò ọbà, ní gúúsù ó gba ilẹ̀ dé Èbúté mẹ́ta, lápá Ìlà Ìwọ̀ oòrùn (Ẹ̀gbádò)
20231101.yo_822_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Orísìí mẹ́rin ni àwọn Ẹ̀gbá tó wà ní Abẹ́òkúta lónìí. Kò parí síbẹ̀ àwọn miiran tún wà tí wọn ti di Ẹ̀gbá lónìí. Sé tí ewé bá pẹ́ lára ọsẹ, kò ní sàì di ọsẹ.
20231101.yo_822_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Èkíní nínú àwọn ẹ̀yà Ẹ̀gbà yìí ni Ẹ̀gbá Aké. Orísìírísìí ìlú ló tẹ̀ ẹ́ dó, ìdí nìyí tí àwọn Ẹ̀gbá tó kù se ń sọ pé “Ẹ̀GBÁ KẸ́GBÁ PỌ̀ LÁKÉ”. Aké ni olú ìlú wọn. Àwọn ìlú tó kù lábẹ́ Ẹ̀gbá Aké ni Ìjokò, Ìjẹùn, Ọ̀bà, Ìgbẹ̀Ìn, Ìjẹmọ̀, Ìtọ̀kú, imọ̀, Emẹ̀rẹ̀, Kéesì, Kéǹta, Ìrò, Erunwọ̀n, Ìtórí, Ìtẹsi, Ìkọpa, Ìpóró ati Ìjákọ.
20231101.yo_822_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ẹ̀gbá òkè-ọnà ló tẹ lẹ́ Ẹ̀gbá Aláké. Osìlè ni ọba wọn, oun ni igbákejì Aláké. Òkò ni olú ìlú wọn. Àwọn ìlú tó kù lábẹ́ Ẹ̀gbá òkè -ọnà ni Ejígbo, Ìkìjà, Ìjẹjà, odo, Ìkèrèkú, Ẹ̀runbẹ̀, Ìfọ́tẹ̀, Erinjà, ilogbo àti Ìkànna.
20231101.yo_822_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ẹ̀gbá Gbágùrá ni orísìí kẹta. Ìdó ni olórí ìlú wọn. Àgùrá si ni ọba wọn. Àwọn Ìlú to kù ni ọ̀wẹ̀, Ìbàdàn, Ìláwọ̀, Ìwéré, òjé ati àwọn ìlú mọ́kàndínlógoji (39) mìírán.Nígbà tí ogun bẹ sílẹ̀ ni mẹ́sàn-án lara ìlú Gbágùrá sá lọ fi orí balẹ̀ fún Ọlọ́yọ̀ọ́ títí di òní yìí. Àwọn ìlú naa ni Aáwẹ́, Kòjòkú Agéníge, Aràn, Fìdítì, Abẹnà, Akínmọ̀ọ́rìn, Ìlọràá àti Ìròkò.
20231101.yo_822_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ẹ̀gbá Òwu ni orísìí kẹrin, Àgó-Òwu ni olú ìlú wọn, Olówu ni ọba wọn, ìlú tó kù lábẹ́ Òwu ni Erùnmu, Òkòlò, Mowó, Àgọ́ ọbà, àti Apòmù.
20231101.yo_822_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Yàtọ̀ sí àwọn tí a sọ̀rọ̀ rẹ lókè yìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà míìràn náà ló pọ̀ ní Ẹ̀gbá tí wọ́n ti di ọmọ onílẹ̀ tipẹ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn báyìí ni a kó lásìkò ogun tàbí kí wọn wá fúnra wọn nígbà tí wọn ń sá àsálà fún ẹ̀mí wọn, tí wọn sì ǹ wá ibi isádi. Irú àwọn báyìí ni Ègùn tí wọn wá ni Àgọ́- Ègùn, Ìjàyè- ni Àgọ́- Ìjàyè, àti àwọn Ìbàràpá ni Ìbẹ̀rẹ̀kòdó àti ni Arínlẹ́sẹ̀. Bákannáà ni àwọn Ẹ̀gbádò wà ní Ìbàrà iléwó, onídà àti oníkólóbó bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn tí sáájú Ẹ̀gbá dó síbẹ̀.
20231101.yo_822_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Láti ìgbà tí àwọn Ẹ̀gbá ti dó sí Abẹ́òkúta ni ètò ìsèlú wọn ti bẹ̀rẹ̀ si yàtọ̀. Ó di pè wọn ń yan ọba kan gẹ́gẹ́ bí olórí gbogbo gbò. Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ọ̀rọ̀ kò rí bẹ́ẹ̀, kọ́lọ́mú dọ́mú Ìyá rẹ gbé ni. Èyí náà ló sì fìyà jẹ wọ́n. ÀÌrìnpọ̀ ejò ló sá ǹ jẹ ejò níyà.Sé bọ́ká bá síwájú, tí pamọ́lẹ̀ tẹ le e, tí baba wọn òjòlá wá ń wọ́ ruru bọ̀ lẹ́yìn, kò sí baba ẹni tó jẹ dúró. Ọ̀rọ̀ “èmi –ò-gbà ìwọ -ò -gbà” yìí ló jẹ́ kí àwọn alábàágbé Ẹ̀gbá maa pòwe mọ́ wọn pe “Ẹ̀gbá kò lólú, gbogbo wọn ló ń se bí ọba” Ọba wá di púpọ̀.
20231101.yo_822_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ìjọba ìlú pín sí ọ̀nà bíi mẹ́rin nígbà tí ọ̀kan wọn balẹ̀ tán ni ibùdó titun yìí. Àkọ́kọ́ nínú wọn ni àwọn Ológbòóni. Ìlú kọ̀ọ̀kan ló ní àwọn ẹgbẹ́ yìí fún ra rẹ̀. Lóòtọ́, ọba ló nilẹ̀, òun ló sì ń gbọ́ ẹjọ́ tó bá tóbi jù. Sị́bẹ̀ síbẹ̀, àwọn Ògbóni lágbára ju ọba lọ. Àwọn ni òsèlú gan-an. Àwọn ló ń pàsẹ ìlú. Wọn lágbára láti yọ ọba lóyè. Delanọ ní láti ilé-ifẹ̀ ni Ẹ̀gbá tí mú ètò Ògbóni wá. Wọn tún un se, wọn sì jẹ́ kí o wúlò tóbẹ́ẹ̀ tí ilé-ifẹ̀ pàápàá ń gáárùn wo ògbóni Ẹ̀gbá.
20231101.yo_822_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Orò ni wọn ń lò láti da sẹ̀ríà fún arúfin ti ẹ̀sẹ̀ rẹ tòbi. Bí orò bá ti ń ké ní oru yóò máa bọ̀ lákọlákọ. Olúwo ni olórí àwọn ògbóni. Àwọn oyè tó kù tó sì se pàtàkì ní Apèènà, Akẹ́rẹ̀, Baàjíkí, Baàlá, Baàjítò, Ọ̀dọ̀fín àti Lísa.
20231101.yo_822_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Àwọn olórógun tún ní àwọn ẹgbẹ́ kejì tó ń tún ìlú tò. Láti inú ẹgbẹ́ àáró tí ọkùnrin kan ti n jẹ Lísàbí dá sẹ́lẹ̀, ní ẹgbẹ́ olórógun ti yọ jáde. Ọjọ́ kẹtàdínlógún kẹtàdínlógún ni wọ́n ń se àpèjọ wọn. Àwọn náà ló gba Ẹ̀gbá kalẹ̀ lọ́wọ́ ìyà tí Ọlọ́yọ̀ọ́ àti àwọn Ìlàrí rẹ fi ń jẹ wọn. Ara àwọn oyè tí wọn ń jẹ ni jagùnà (ajagun lójú ọ̀nà) olúkọ̀tún (olú tí Í ko ogun òtún lójú), Akíngbógun, Òsíẹ̀lẹ̀ àti Akílẹ́gun. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni wọn si ti sẹ.
20231101.yo_822_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Àwọn pàràkòyí náà tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì tí ọrọ ba di ti ọrọ̀ ajé àti ìsèlú. Àwọn ni n parí ìjà lọ́jà, àwọn ló n gbowó ìsọ ̀. Asíwájú àwọn pàràkòyí ni olórí pàràkòyí.
20231101.yo_822_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Àwọn ọdẹ pàápàá tún jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn atúnlùútò. Wọ́n ń dá ogun jà nígbà mìíràn. Àwọn ni wọn n sọ ọjà àti gbogbo ìlú lóru.
20231101.yo_822_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Àwọn olóyè ọdẹ jàǹjàǹkàn naa a maa ba àwọn tó wà ní ìgbìmọ̀ ìlú pésẹ̀ fún àpérò pàtàkì. Díẹ̀ lára oyè tí wọn n jẹ ni Asípa, olúọ́dẹ àti Àró ọdẹ.
20231101.yo_822_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Bí ọ̀rọ̀ kan ba n di èyí ti apá lé ko ka, o di ọdọ olórí àdúgbò nì yẹn. Bí kò bá tún ni ojútùú níbẹ̀, a jẹ́ pé ó di tìlùú nì yẹn ọba lo maa n dájọ́ irú èyí nígbà náà.
20231101.yo_822_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Tí a bá ka a ni ẹní , èjì ó di ọba mẹsan an to ti jẹ láti ìgbà ti wọn ti de sí Abẹ́òkúta. Àwọn náà nìwọ̀n yii:
20231101.yo_822_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Yàtọ̀ sí ọba Aláké tí a to orúkọ wọn sókè yìí, ọba mẹ́rin míìrán tún sì wà ní Abẹ́òkúta tí wọn ń se olórí ìlú wọn. Sùgbọ́n, gbogbo wọn tún sì wà lábẹ́ aláké gẹ́gẹ́ bii ọba gbogbo gbò ni. Àwọn ọba náà ni, Àgùrà Olówu, Òsilẹ̀ àti olúbarà. Ọba aládé sì ni gbogbo wọn. Ní ti oyè tó kù nílùú, o ní agbára tí wọn fún ìlú kọ̀ọ̀kan láti fi olóyè sílẹ̀. Ẹ̀gbá òkè- ọnà ló ń yan ọ̀tún ọba. Ẹ̀gbá Gbágùrá lo n fi òsì àti Òdọ̀fin sílẹ̀. Ẹ̀gbá Òwu lo si n yan Ẹ̀kẹrin ìlú.
20231101.yo_822_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn jàǹkànjàǹkàn tó ti fi ẹ̀mí wọn wu ewu fún Ẹ̀gbá ni wọ́n máa ń ráńtí nínú gbogbo orin wọn. Wọn a sì máa fi orúkọ wọn búra pàápàá. Irú àwọn báyìí ni Sódẹkẹ́, Lísàbí, Ẹfúnróyè, Tinúubú ati Ògúndìpẹ̀ Alátise. Àwọn Ẹ̀gbá kò kó iyán wọn kéré wọn kò sì yé bu ọlá fún wọn bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti kú.
20231101.yo_822_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Orísìírìsìí isé ajé ni àwọn Ẹ̀gbá n mú se nínú ìlú. Yàtọ̀ sí isẹ́ àgbẹ̀ tó jẹ́ tajá tẹran ló ń seé wọ́n fẹràn láti máa da aró, wọ́n mọ̀ nípa àdìrẹ ẹlẹ́kọ dáadáa. Wọ́n tún nífẹ̀ẹ́ si òwò síse. Àwọn àbọ̀ ilẹ̀ sàró ni ó jẹ́ kí ọ̀rọ̀ òwò síse yìí túbọ̀ gbilẹ̀ tó bẹ́ẹ̀. Kò sí ìlú kan tí kò ní ọjà tirẹ̀, sùgbọ́n àwọn ọjà ń lá kan wà tó ti di ti gbogbo gbo. Irú àwọn ọjà báyìí ni Ìtọ̀kú, Ìta Ẹlẹ́gà, ọjà ọba àti Ìbẹ̀rẹ̀kòdó. Paríparí rẹ̀ àwọn Ẹ̀gbá fẹ́ràn láti máa kọrin lásán.yálà kíkọ tà gẹ́gẹ́ bí alágbe tàbí ìfẹ́ láti máa kọrin lásán. Gbogbo ohun tó sì ti sẹlẹ̀ sí àwọn baba ńlá wọn ni wọ́n máa ń mú lò nínú orin wọn pàápàá.
20231101.yo_822_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Lọ́nà kìnní, gbogbo Ẹ̀gbá ló gbà Abẹ́òkúta sí ìlú wọn.Wọn ni ilẹ̀ níbẹ̀, sùgbọ́n wọn a máa lọ sí ẹ̀yìn odi ìlú láti lọ múlẹ̀ oko. Ní ìparí ọ̀sẹ̀ ni wọ́n ń wálé. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ irú oko ẹ̀yìn odi ìlú báyìí lo ti di ìlú fún wọn. Abúlé ni wọn n pe àwọn ìletò wọ̀nyí. Kò sí ọmọ Ẹ̀gbá kan tí kò ní abúlé . Ètò abúlé wọ́ pọ̀, ó sì gún régé, Baálẹ̀ tàbí olóróko (olórí oko) ni o wà ní ipò ọ̀wọ̀ jùlọ.
20231101.yo_822_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Bákan náà ló jẹ́ pé gbogbo wọn lo jọ ń bú ọlá fún àwọn ẹni ńlá wọn. Kò sí pé apá kan kò ka àwọn ẹni àná yìí wọ̀nyìí́ kún.
20231101.yo_822_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Orò tún jẹ́ ẹ̀sìn kan tó so wọ́n pọ̀. Nílélóko ni wọn ti ń sọdún orò lọ́dọọdún. Àwọn olórò ìlú kan lè mú orò wọn dé ìlú mìíràn láìsí ìjà láìsí ìta. Lóòótọ́, ìlú kọ̀ọ̀kan ló ní òrìsà tirẹ̀ tó se pàtàkì, fún àpẹẹrẹ, àwọn Òwu ló ni Òtòǹpòrò àti Ẹlúkú. Àwọn Odò ọnà ló ni Agẹmọ, àwọn ìbarà lo ni Gẹ̀lẹ̀dẹ́. Òrìsà Àdáátán, ọ̀tọ̀ ni. O máa ń sẹlẹ̀ ni ọ̀pọ̀ ìgbà pé tí ìlú kan bá parí ọdún tiwọn lónìí, tí àdúgbò míìràn le bẹ̀rẹ̀ ni ọjọ́ keje ẹ̀. Èyí kò sí yi padà láti ọjọ́ pípẹ́ wá.
20231101.yo_822_34
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
Ọjà kan náà ni wọn jọ́ ń ná, oúnjẹ ti wọn ń jẹ ní Aké ni wọn ń jẹ ní Òkò. Wọn fẹ́ràn àmàlà láfún púpọ̀. Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń jẹ Sapala kòkò, ewé, awújẹ àti èsúrú.
20231101.yo_822_35
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ab%E1%BA%B9%CC%81%C3%B2k%C3%BAta
Abẹ́òkúta
“Mo lérò pé pẹ̀lú gbogbo àlàyé mi òkè yìí ìrànlọ́wọ́ ni yóò jẹ fún àwọn ohun ti a ó ò máa kan nínú orin Ògóló níwájú, àwọn ọ̀rọ̀ tí ìbá si ru ni lójú tẹ́lẹ̀ ni yóò di ohun ti yóò tètè yé ni”.
20231101.yo_1590_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%BA%B8%CC%80k%E1%BB%8D
Ẹ̀kọ
Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmò ní Nàìjíríà, tí wón sì ń fi àgbàdo, ọkà tàbí jéró se. Bí wọ́n bá fẹ́ se ògì, wọ́n á rẹ àgbàdo,, ọkà tàbí jéró sínú omi fún ọjọ́ méjì sí mẹta kí wón tó lọ̀ ọ́, lẹ́yìn náà, wọ́n ọ́ fi kalè fún bi ọjọ́ mẹta miran láti kan, lẹ́yìn èyí, wón le sè é. Wọ́n ma ń fi àkàrà, moin moin àti àwọn ounjẹ míràn mu ogi.
20231101.yo_1754_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ogun
Ogun
Ogun Ẹkú dédé àsìkò yìí ẹ̀yin ọmọ ogun. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ jẹ́kí á tún bọ̀ sọwọ́pọ̀ láti gbé ògo ilẹ̀ Yorùbá ga.Inù mi dùn púpọ̀ sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀ẹ̀tí kẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá yálà nílẹ̀ Yorùbá tàbí ní òkè òkun bá lè bẹ̀rẹ̀ láti máa kọ́ ọ̀pọlọ̀pọ̀ nínú àwọn àròkọ wọn ní èdè abínibí wà nítorí òní kọ́ àmọ́ nítorí ọjọ́ ọ̀la kí àwọn ọmọ tí wọn kò ì tíì bí lè rí nnkan kà nípa gbogbo ohun mère mère tí ó n sẹlẹ̀ jákè jádò àgbáyé.
20231101.yo_1754_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ogun
Ogun
Tí a bá wo àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sì ní máa gbérí níwọ̀n ọgbọ́n ọdún sẹ́yìn a ri wí pé púpọ̀ nínú wọn ni wọn fi èdè abínibí kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọ́n, kòsí iṣẹ́ìwádìí kan tí wọ́n se tí wọ́n kò kọ ní èdè wọn bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé èdè gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n gbà fi se ìwádìí náà.
20231101.yo_1754_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ogun
Ogun
Ó seni láànu láti máa pàdé àwọn ara ilé nílu òyìnbó kí wọ́n máa fara pamọ́ ki a máà ba pè wọ́n ní ọmọ Yorùbá.Ogún lọ́gọ̀ àwọn olùkọ́ni nílu òyìnbó ni wọ́n jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá sùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo akitiyan wọn kò sí ọ̀kan soso nínú isẹ́ ìwádìí wọ́n pẹ̀lú aroko tí ó wà ní èdè Yorùbá-
20231101.yo_1835_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Orílẹ̀-èdè Ìṣọ̀kan àwọn Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà tabi Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (USA tabi US ní sọ́kí ní gẹ̀ẹ́sì), tàbí Amerika ni soki, jẹ́ orílé-èdè ijoba àpapò olominira pèlú iwe-ofin ibagbepo tí ó ni adota ipinle, agbegbe ijoba-apapo kan ati agbegbe merinla, ti o wa ni Ariwa Amerika. Ilẹ̀ re fe lati Òkun Pasifiki ni apa iwoorun de Òkun Atlántíkì ni apa ilaorun. O ni bode pelu ile Kanada ni apa ariwa ati pelu Meksiko ni apa guusu. Ipinle Alaska wa ni ariwaiwoorun, pelu Kanada ni ilaorun re ati Rosia ni iwoorun niwaju Bering Strait. Ipinle Hawaii je agbajo erekusu ni arin Pasifiki. Orile-ede awon Ipinle Aparapo tun ni opolopo agbegbe ni Karibeani ati Pasifiki.
20231101.yo_1835_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Pelu 3.79 egbegberun ilopomeji maili (9.83 million km2) ati iye to ju 309 egbegberun eniyan lo, awon Ipinle Aparapo je orile-ede totobijulo keta tabi kerin bii apapo iye aala, ati iketa totobijulo bii aala ile ati bi awon olugbe. O je kan ninu awon orile-ede agbaye to ni opolopo eya eniyan ati asapupo, eyi je nitori ikoreokere lati opo awon orile-ede. Okowo awon Ipinle Aparapo ni okowo orile-ede to tobijulo lagbaye, pelu idiye GIO 2009 to je $14.3 egbegberunketa (idamerin GIO oloruko lagbaye ati idamarun GIO agbaye fun ipin agbara iraja).
20231101.yo_1835_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Awon eniyan abinibi ti won wa lati Asia ti budo si ori ibi ti orile-ede awon Ipinle Aparapo wa loni fun egberun lopo odun. Awon olugbe Abinibi ara Amerika din niye gidigidi nitori arun ati igbogunti leyin ibapade awon ara Europe. Orile-ede awon Ipinle Aparapo je didasile latowo awon ileamusin metala ti Britani to budo si egbe Okun Atlantiki. Ni ojo 4 Osu Keje, 1776, won se Ifilole Ilominira, eyi kede eto won fun iko araeni ati idasile isokan alafowosowopo won. Awon ipinle asagun yi bori Ileobaluaye Britani ninu Ogun Ijidide Amerika, eyi ni ogun alamusin fun ilominira akoko to yori si rere. Ilana-ibagbepo ile awon Ipinle Aparapo lowolowo je gbigba bi ofin ni ojo 17 Osu Kesan, 1787; itowobosi ni odun to tele so awon ipinle di apa orile-ede olominira kan na pelu ijoba apapo to lagbara. Awon Isofin awon Eto, to ni atunse mewa si ilana-ibagbepo ti won semudaju awon eto ati ainidekun araalu, je titowobosi ni 1791.
20231101.yo_1835_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Ni orundun 19th, awon Ipinle Aparapo gba ile lowo France, Spain, Ileoba Aparapo, Mexico, ati Rosia, o si sefamora Ile Olominira Teksas ati Ile Olominira Hawaii. Ijiyan larin awon ipinle ni Guusu ati awon ipinle ni Ariwa lori awon eto awon ipinle ati igbegun oko eru lo fa Ogun Abele Amerika ti awon odun 1860. Isegun ti Ariwa dena ipinya, o si fa opin oko eru ni Amerika. Nigba ti yio fi to awon odun 1870, okowo orile-ede awon Ipinle Aparapo ile Amerika ni eyi ti o tobijulo lagbaye. Ogun Spein ati Amerika ati Ogun Agbaye Akoko so Amerika di orile-ede alagbara ologun. Leyin Ogun Agbaye Keji o di orile-ede akoko to ni ifija inuatomu, o si tun di omo egbe tikoye ni Ileigbimo Abo Agbajo awon Orile-ede Aparapo. Opin Ogun Koro ati Isokan Sofieti mu ki awon Ipinle Aparapo o di orile-ede alagbara nikan to ku. Amerika siro fun idameji ninu marun inawo ologun lagbaye be sini o tun je akopa asiwaju ninu okowo, oloselu ati asa lagbaye.
20231101.yo_1835_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Ni 1507, Martin Waldseemüller ayamaapu ara Jemani pese maapu lori ibi to ti pe oruko awon ile ti won wa ni Ibiilaji Apaiwoorun bi "Amerika" lati inu oruko oluwakiriri ati ayamaapu ara Italia Amerigo Vespucci. Awon ibiamusin Britani tele metala koko lo oruko orile-ede yi ninu Ifilole Ilominira, bi "Ifilole alafenuko awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("unanimous Declaration of the thirteen united States of America") to je gbigba mu latowo "Awon Asoju awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("Representatives of the united States of America") ni ojo 4 Osu Keje, 1776. Ni ojo 15 Osu Kokanla, 1777, Ipejo Olorile Keji gba awon Ese-oro Ikorapapo, to so pe, "Oruko Ijekorapapo yi yio je 'Awon Ipinle Aparapo ile Amerika'" ("The Stile of this Confederacy shall be 'The United States of America.'") Awon iwe adehun lari Fransi ati Amerika odun 1778 lo "Awon Ipinle Aparapo ile Ariwa Amerika ("United States of North America"), sugbon lati ojo 11 Osu Keje, 1778, "Awon Ipinle Aparapo ile Amerika" ("United States of America") lo je lilo lori awon owo fun pasiparo, latigbana eyi lo ti je oruko onibise re.
20231101.yo_1835_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Ni ede Yoruba "Orile-ede Amerika" tabi "Amerika" lasan loruko to wopo. A tun le lo lo "U.S." tabi "USA".
20231101.yo_1835_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Amerika ni bode po mo Kanada, to gun lapapo to 8895 km (pelu bode larin Kanada ati Alaska to to 2477 km), o tun ni bode mo Meksico, to gun to 3326 km. Iye apapo igun bode Amerika je 12,221 km. Bakanna etiodo mo Atlantiki, Pasifiki ati Ikun-omi Meksiko na tun ni iye apapo to to 19,924 km.
20231101.yo_1835_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Aala ori ile Amerika je 9,161,924 km2 pelu aala ori omi to to 664,706 km2, gbogbo aala ile Amerika je 9.82663 egbegberun km2.
20231101.yo_1835_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Ifagun ariwa-guusu re lati bode mo Kanada ati bode mo Meksiko je 2,500 km, ifagun ilaorun-iwoorun lati eti Okun Atlantiki de Psifiki je 4,500. Orile-ede Amerika dubule si arin ilagbolojo apaariwa 24 ati 49 ati larin ilaninaro apaiwoorun 68th ati 125, be sini o pin si akókò ilẹ̀àmùrè merin.
20231101.yo_1835_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Aala orile-ede Amerika ni ilafiwo to yato pato. Awon oke ileru bi Cascade Range, ati oke alokoro bi Rocky Mountains ati Appalachian Mountains wa lati Ariwa de Guusu. O ni odo bi Odo Misissipi ati Missouri. O ni opo ile gbigbe ati ile koriko.
20231101.yo_1835_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%A8d%C3%A8%20America
Orílẹ̀ èdè America
Ojuojo duro lori ibudo. Lati ileolooru ni Florida titi de tundra ni Alaska. Opo ibi ni won ni ooru ni igba eerun ati otutu ni igba oye. Awon ibomiran tun wa bi California ti won ni ojuojo Mediteraneani. Ojuojo oloro ko wopo. Awon ipinle ti won bode mo Ikun-omi Meksiko ni iji are prone to hurricanes, and most of the world's tornadoes occur within the country, mainly in the Midwest's Tornado Alley.
20231101.yo_1839_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/J%E1%BA%B9%CC%81m%C3%A1n%C3%AC
Jẹ́mánì
|footnote1= Danish, Low German, Sorbian, Romany and Frisian are officially recognised and protected by the ECRML.
20231101.yo_1839_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/J%E1%BA%B9%CC%81m%C3%A1n%C3%AC
Jẹ́mánì
Jẹ́mánì (), fun ibise gege bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Jẹ́mánì (, ), je orile-ede ni orile Arin Europe.
20231101.yo_1839_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/J%E1%BA%B9%CC%81m%C3%A1n%C3%AC
Jẹ́mánì
Jemani pin si awon ipinle 16 (Bundesländer), awon wonyi si tun je pinpin si agbegbe ati ilu 439 (Kreise) ati (kreisfreie Städte'').
20231101.yo_1846_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́ ti a dá s’ílẹ̀ ní ìlú Beijing, Shaina ní ọdún 1917, jẹ́ ìjọ t’ó dá dúró nínú àwọn oní-pẹ́ntíkọ́stì. Ìjọ yìí faramọ́ ìkọ́ni “ọ̀kan soso l’Ọlọ́run”. Wọ́n gbàgbọ́ pé ọ̀kan l’Ọlọ́run àti pé Jésu jẹ́ Ọlọ́run. Ìjọ yìí kọ ìkọ́ni “mẹ́tal’ọ́kan” pé kò tọ́, kò sì dọ́gba láti s’àpèjúwe Ọlọ́run. Ìjọ gbà pé ìkọ́ni “mẹ́tal’ọ́kan” kò wá láti inú Bíbélì nìkan sùgbọ́n láti inú àwọn orísirísi àfikún lẹ́yin àkojo Bíbélì, èyí tí àwọn olùtèlé “ọ̀kan soso l’Ọlọ́run” kà sí èrò èniyàn lásán, tí kò ní àsẹ ìmísi Ọlọ́run bíi ti Bíbélì.
20231101.yo_1846_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kà á sí ìjọ àwọn ará Sháínà, “Ìjọ Jéésù Lótìítọ́” lóde òní tí ó n tàn kálẹ̀ àgbáye bí a ti n wàásù ìhìnrere Jéésù kárí ayé. Iye àwọn olùtèlé “Ìjọ Jéésù Lótìítọ́” jẹ́ ẹgbèrún lọ́nà ẹgbàá mẹ́jọ èniyàn ní orílẹ̀ kọ́ntínẹ́ntì mẹ́fà ní àgbáyé.
20231101.yo_1846_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Emi Mimo: Gbigba emimimo, aridaju nipa fifi ede titun soro, eleyi je idaniloju ipin wa ni ijoba orun.
20231101.yo_1846_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Iribomi: Iribomi jẹ́ ise fun irapada ese lati irandiran. Iribomi n waye ninu omi bi Odo, Okun tabi omi ti n san. Eni ti a ti se iribomi ti omi ati tie mi mimo no o n se iribomi yii fun elomiran ni oruko Olwa wa Jésù Kristi. Eni ti a n se iribomi fun gbodo je riri bo omi patapata pelu ori ti yio teriba sinu omi.
20231101.yo_1846_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Ise ti fifo ese: Ise ti fifo ese jẹ́ ki eniyan ni ipin pelu Jésù Kristi. O si jẹ́ ohun iranti wipe eniyan gbodo ni ife, ije-mimo, iteriba, idariji ati ise iranse. Gbogbo eniyan ti a ti ri bo omi ye ki a we ese re ni oruko Jesu Kristi. Ise ki onikaluku we ese ominikeji re jẹ́ ohun ti o ye ki o di sise nigba ti o ba to.
20231101.yo_1846_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Ounje ale Oluwa: Ounje ale Oluwa jẹ́ sise fun iranti iku Jesus Kristi Oluwa wa. O jẹ́ ki a jẹ́ alabapin ninu eran ara ati eje Oluwa wa lati jẹ́ alajopin ninu iye ayeraye ki a si ji dide ninu oku ní ojo keyin. A gbodo ma se eleyi ni gbogbo igba. Buredi ati omi eso ‘girepu’ ní a oo lo.
20231101.yo_1846_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Ojo Isinmi: Ojo Isinmi, Ojo keje ose (Satide), je ojo mimo ti Ọlọ́run ya si mimo. Ojo yi jẹ́ yiyasoto ni abe ore ofe Olorun fun iranti awon eda Ọlọ́run ati igbala won pelu Ireti Isinmi ayeraye ni aye ti n bowa.
20231101.yo_1846_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Jésù Kristi: Jésù Kristi, oro naa ti o di eran-ara, ku fun wa ni ori igi agbelebu fun irapada elese, a jii dide ní ojo keta, o goke re orun. Ohun nikan ni olugbala araye, eleda orun oun aye, Olorun otiti kan soso.
20231101.yo_1846_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Iwe mimo: Iwe mimo, ninu re ni a ri Majemu Lailai ati Majemu titun, imisi eleyi ti o wa lati odo Ọlọ́run, iwe ododo kan soso ati ilana tooto fun igbe aye kristieni.
20231101.yo_1846_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Igbala: Igbala jẹ́ ohun ti a fifunni nipa Ore ofe Ọlọ́run nipase Igbagbo. Onigbagbo gbodo fi ara tan emi-mimo lati lepa Ije mimo, lati bowo fun Olorun ati lati fe ohun eda Ọlọ́run.
20231101.yo_1846_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Ijo mimo Jésù: Ijo mimo Jésù, ifilole lati owo Jésù Kristi wa, nipase emi mimo ní akoko “ojo ikeyin” ni ipadabosipo ijo tooto ti igba awon aposteli.
20231101.yo_1846_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cj%E1%BB%8D%20J%C3%A9%C3%A9s%C3%B9%20L%C3%B3t%C3%AC%C3%ADt%E1%BB%8D%CC%81
Ìjọ Jéésù Lótìítọ́
Ipadabo Jésù kriti: Ipadabo Jésù kriti yio sele ní ojo ikeyin nigba ti O ba sokale lati orun wa lati da aye ní ejo: olododo yio jogun iye ainipeku, nigbati awon eni buburu yio jogun iparun ayeraye.
20231101.yo_2050_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Koríko ìkólé ti a ń pè ní ìken nì èdè Rémo ni ó wópò púpò ní agbegbe kan nì ayé ojoún. Nìgbà ti ó wà dì wí pé awoòn ènìyàn ń gbé agbègbè yìí bí ìlú ni won bá n so wí pé a tun ni ni ikèn néè o. èyí ti a wa se ìsúnkì gbólohùn náà sí ìkènné.
20231101.yo_2050_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Òkunrìn jagunjagun kan ni àdúgbò yìí ni ó ka ení rè kan mo ibi ti ó tí n kínrin aya re ken leyin nigbati aránbìnrin náà ń wè ní ile iwe. Inu bi okunrin yìí pàápàá nitori pe erúbinrin náà kò sá nìgbà ti é rí ì. Èyí mu kì ó bínu pa ìyàwó rè àti erúbìnrin náà Nìgbà ti won sì bì í ìdí ti ó fi se béè o sàlàyé pé ń se ni erú yìí sànyín-dó. Lati ìgbà náà ni a ti ń pe adugbo ohun ní sànyìndó.
20231101.yo_2050_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Nì ayé àtijó, òwúrò kùtùkùtù ni won máa ń ná ojà agbègbè kan báyìí ni ìlè Remo. Kèrèkèrè, awon ènìyàn bèrè sí ìlé ní í ko sí ibi ofà yii, wón sì ń gbé ibe. Bayìí ni won se so ojà náà ní Ajino ti àwon ènìyàn sì so adugbo náà nì Ajìwo titi di ìsìnsìnyí.
20231101.yo_2050_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Agbègbè ti a fi igi Obì pààlà tàbí sàmì sí. Àwon méjì ti ó ń jà du ààlà ilè ni o fa orúko yìí jáde nítorí awon tì ó nì ìlè salàyé wí pé ìgi obì ni àwon fì dó: ìlè àwon láti fi se idámo sí ilè elòmìíràn.
20231101.yo_2050_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Ní asìko ogun ti awon Yorùbá ń ti ibi kan dé ibì kan ni àwon kan ko ara won jò láti te ìlú tìtun dó. Léyin ti awon ènìyàn ti n pò níbe ni wòn wa so ìbùdó won yìí ní ‘Ìdótùn’ èyí ti ó túmò sí ibùdó tìtun.
20231101.yo_2050_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Nítorí àgbára àti ìwa ìpàǹle tàbí ìwà jàgídíjàgan okunrin kan báyìí ti a pe orùko rè ní Ìdó ni àsìkò Ojoun ni a se so oruko adugbo yìí ní Ìdómolè léyìn ikù okunrin yìí ni awon ènìyàn bérè sì fi okunrin yìí júwè adúgbò ré. Won a ní awon n lo sí Ìdó akínkayú nì tàbí okùnrin imolè nì. Báyìí ni a kuku so adúgbà di Ìdómolè.
20231101.yo_2050_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Léyìn ìgbà ti awon Yorùbá ken ti gbà latí parapò máa gbe pèlu ìrépò ni agbègbè kémo, yìí ni won kùkú wá pè è ní Ìrolù. Èyí túmo sì pé awon jo kò ó lù ni kí àwón tó ‘péjo síbè.
20231101.yo_2050_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Àwon ìlu méta ni ó parapò sí ojú kan. Nígbà tí ó wà di wì pé okan kò yòǹda oruko tirè oún èkèjì ni wón wà yo nínú oruko awon meteeta; làti yo sàaàpàde
20231101.yo_2050_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Òde nì awon tí ó parapò te ìlú ìsara dó. Kaluku awon ènìyàn wònyi ni won sì wá láti agbègbè òtòòtó. Nígbà ti ó wá dì wí pè ènìkan fé so ara re di olorí ‘àpàpàndodo ni won bá làá yée pe n se nì awon sa ara awon jo sibe! Ti won sì ‘sun orúkò náà kì di Isarà.
20231101.yo_2050_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Áwon tí ó ń gbé òkèèrè ni won ti kèrèkèrè só dì ògèrè. Láyé àtijó bì ó bà ti dì wí pé awon ènìyàn Remo bà fé lo sí ibi ti awon are ‘Ògèrè wá won a so wí pè awon fe ló sí agbègbè awon ara òkèèrè. Awon ènìyàn wònyí búrú púpò jù, won sì taari won sìwaju. Won á ni Okeere ni ó ye won. Nígbà ti ójú ń là nì wón bà so oruko ìlú yìí di Ògèrè.
20231101.yo_2050_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Ìyá kan wà tí ó ń gbe àdúgbò yìí ni ayé ojoun. Kó sì ìgbà ti àwon ènìyàn dé òdò rè tí kìí ni oúnje àdi`dùn. Nìgbà ti ò dì wí pe gbogbo ènìyàn bere si fi ounje ìyà yìí júwè adúgbò naa ni wòn kúkú wa n pe adugbo yìí ní Ajítáádùn (Ají-ta-dídùn).
20231101.yo_2050_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtunmò: Ni ìgbà láéláé, ìtàn so fún wa pé omo kan sonù tí kiri títí, léyìn tí wón ti wáa kiri títí ni wón ríini ìlú ken tí ó jìnà. Nítorí pé ibi tí wón ti rí omo náà jìnà, ni wón se ń pè ní ìlúgùn.
20231101.yo_2050_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
[Àgó Òkò]: Òkúta ni wón ń pè ní òkò nì èka èdè ègbá. Ní ìgbà ogun, awon ará àdúgbò yìí ko ni ohun elo ìjà kankan ayàfi òkúta. Òkò ni wón má a ń so fún àwon ota won. Ìdí nìyí tí wón fi ń pè wòn ní Àgó Òkò
20231101.yo_2050_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtokò: Adágbà je omo ìrówò ìbàràpá òun ní ó kókó dé Abéòkúta, Ogun lé won dé orí dímo (Àwon ìbàràpá) wón bá Adágbà tí ó ń se isé ode ní orí olúmo. Adágbà fi àwon ìbàràpá tí ogun lé dé ori olúmo yìí sí ìdi igi ìto kan. Àwon náà bèrè sí í se ode. Ní ojó kan wón ro oko yí ìdi igi ìto yìí ká, wón gbá pàǹtí sí abé igí ìto yìí, wón fi iná sí i. Nígbà tí Adágbà rí i, ó pariwo lé won lórì pé: Ah! Èyin ènìyàn yìí ìto le kò (Kò túmò sí kí á pa igi). Bí a se rí ìtokò nì yí.
20231101.yo_2050_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Kémta: Kémta tumo sì kèeta, Àsòjóró, òtè. Wón máa ń se keèta ara won ìdí èyí ni wón fi ń pe wòn ni kémta.
20231101.yo_2050_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Àgó òwu: Àwon ará àdúgbò yìí jé àwon tí ó ń jowú, owú jíje won ló mú won sokún gba adé àwon omo ìkijà. Ìdí nìyí tí wón se ń ki won pé “Ara òwu, omo asunkún gbadé
20231101.yo_2050_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Arégbà: Àdúgbò tí àwon ìbàràpá tèdó sí. Nígbà tí wón dífá pé kí wón mú Ègbá wá. Wón ní ati-re-gbà ó. Bí ó se dí arégbà nìyí.
20231101.yo_2050_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Kúgbà: Ikú-gba-èyí. Odò ńlá kan tí ó gbé omo lo ní Arégbà ní àwon ènìyàn ìgbà náà fi ń so pé íkú gba èyí lówó wa. Kúgbà.
20231101.yo_2050_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Òkè Èfòn: Àwon ará Efòn Alàyè láti ìpínlè Òǹdó ni wón ń gbé àdúgbò yìí. ìdí nìyí tí a fi ń pè àdúgbò náà ní òkè èfòn.
20231101.yo_2050_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Àdátán: Ogun àti oko ríro, léyìn tí wón tí ja ogun tán, wón fé roko àyíká àdúgbò náà ní a so fún òkunrìn kan pé kí ó lo mú Àdá láti fi sisé wá. Òle ènìyàn nì okùnrin yìí, ó dáhún, ó ní Àdá ti tán. Bayìí ni a se ń pe ibè ní Àdátá.
20231101.yo_2050_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Sábó: Sábó wá láti inú Sábánímó. Àdúgbò tí àwon Hausa tèdó si ni. Òrò yìí kì í se òrò Yorùbá tàbí ti Ègbá.
20231101.yo_2050_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Odédá: Àdúgbò tí àwon ode má a ń fàbò sí lèyìn tí wón bá ti sode lo tán ni ibè ní won yóò péjo sí tí won yóò sì dá àwon eran tí wón bá pa jo sí ibè.
20231101.yo_2050_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Òkè Agbède: Àdúgbò yìí ni àwon ìbàdàn tí wón wá sí Abéòkúta tèdó sí ní igbà tí wón wòlú Egbá. Won kò gba ará ìlú mìíràn móra níbè àfi omo ìbàdàn.
20231101.yo_2050_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìsàle Jagun: Ìsàlè (AJAGUN) – Àdúgbò tí wón ti ń ja ogun ní ìlú Ègbá ní ìgbà àtijo. Kòtò wà ní ibè nì wón fi ń pè é ní ìsàlè jagun.
20231101.yo_2050_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Eléwéran: Ewé iran tí a fi ń pón èbà tàbí àmàlà ní o hù àyíká yìí ni ìgbà tó tip é láé. Ibè nì àgó olópàá wà ní Abéòkúta.
20231101.yo_2050_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtumò: Igì ken wa ti èso rè máa ń dún bì ìgbà ti ènìyàn bá ń mi beere. Ibì tì igi yìí wà gan-an ní gbogbo ènìyàn si máa n lo lati mú u fún lìlò ni awón ara ìlú fún ni orúko ti ó jò mo dídún tie so inu rè màa ń dun. – Pasiséké
20231101.yo_2050_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Àwon ará Òkè-Ìdó ni Abéòkúta nìkan ni ó mo awo ti ó wà nínú àgbùdo gbíngbìn. Odò won sì ni gbogbo awon ènìyàn ti máa ǹ ra àgbàdo. Nítorí ìyànje yìí nì Oba Aláké se fun Olórí àdúgbò yìí ni Omobìnrin re kan lati fi se aya. Obinrin yìí ni o ridìí àsiri ìkòkò yìí tì ó sì sàlàyé fún awon ènìyàn rè. Ibì ti arabinrin yìí wà pàdà nì Oko si ni a fùn ni orunko yìí. Mókólà – Omo ko olá wá sílé.
20231101.yo_2050_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Iyá ken ni ò ń dààmú awon ara àdùgbò ìbi ti ó n gbé. Nìgba ti idààmú yìí wá pòju tí awon ènìyàn si mú ejo rè to Oba lo ni ìyá yìí wá sàlàyé wì pé lóòótò ni òún jé àjé ati wì pé ení ti ó bat ó òun ni òún ń da sèrìyà oún. Kábiyèbi bà so pé àsàjemátèe ni obìnrin yìí o. Bi wòn se ń fi ìyá yìí fúwe àdùgbò tì ó ń gbé nìyèn. Won a ní àwón ń lo sí sàje:
20231101.yo_2050_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Àdugbò yìí ni awon òyìnbó tédò sí làtí máa fo òkútà si wéwé oún ilé kíko tàbi òná sise. Awon Òyìnbó yìí ni wón n pè ni Òyìnbó Quarry nítori Orúko òyìnbo ti ó koko gbé àdùgbò yen. Won ní àwon ń lo sí agbègbè Qùarry.
20231101.yo_2050_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Ní àsìkò Ogun nígbà ti ogun tú awon ènìyàn Owu ti onìkàlùkù won sì fónká. Awon ti ó tédó sí àdúgbò yìí ni o kúkú fé se ìdámò ara won si awon Ègbà yookù. Ìdí nìyìí ti won fí so Ibùdó won nì Àgó Òwù Àgò ti a tì ilè rí awon ara Owù
20231101.yo_2050_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Ní àtijó àdúgbò kookan ni ó ní ise ìdamo won. ‘Sùgbón nì tí awon ara àdúgbò yìí eko nì gbogbo awaon obìnrin won màá ń tà. Bí ó bà sì dì ale gbogbo won a pate eko won sì ojú kan. Bì a bá wà rí ení ti o bá fe lo sí ojúde yìí onítòhùn yòó sò pé òun lo si Ìtà-eko. Orúko yìí nì ò sì mo àdúgbò náà lòrí dì onì yìí ni pàtàkí fún ìdamò ìta-eko ojóun.
20231101.yo_2050_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Akínkanjú obinrin kan wa ni Ègbá ni ayé ojóun. Efúnróyè Tínubú nì orúko rè. ‘Nítorí ibe ìdàgbàsòkè re sù ìlú Ègbá ni oba Àláké se fí jè Ìjatóde ìlù. Oún ni ìyálódè Ègbá àkòkó. Ibì ti Ìyá yìí wá kólé sí ní àdúgbò rè ni won so di ‘Ita ìyálódè.
20231101.yo_2050_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Nì àyé àtíjó àbikú ń da bàbá kan láàmu. Nigbà ti ó dáfá, won ni ki ó fe síwáju bì ó bà ń fé kì àbìkú dúró. Bàbá yìí wá dó sí ìbi ti a mo sí Kútò lónìí. Sùgbon léyìn odún díè omo ti ó bà tún kú nì o bá bérè ariwo pé ikú tun to òun léyìn dé ibí yìí. Báyìí ni awon elégbe rè se ge orúko kéré di`kútò tí ó sì wà dòní yìí
20231101.yo_2050_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%ADl%E1%BA%B9%CC%80-ede%C3%A9%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Orílẹ̀-edeé Yorùbá
Ìtùmò: Nígbà tì kò tíì sí ònà móto bí àwon ti a ní lònìí yìí àwon ènìyàn ti wón jè yálà ode tàbí àgbè a máa fi adúgbò Ìdí Àbà se ìpàdé won. Igi àbà po ni àdúgbò yìí nìgbà náà. Awon ènìyàn wonyi a sì maa sinmi ni àbe àwon Ìgi yìí yàlà ní àlo tabì ní àbò. Báyìí nì won se kúkú so agbégbè yìí ni Idí àbà. Bì ó file jè pé olàjú ti dé báyìí èyí kò yí oruko adugbo náà páde dì báyìí.
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
34